Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ká lè borí àwọn ìṣòro tá à ń dojú kọ lónìí, àfi kí Jèhófà ràn wá lọ́wọ́. Torí náà, àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká rí i pé Jèhófà máa ń bójú tó àwọn èèyàn rẹ̀. Ó ń rí gbogbo ìṣòro tí ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ń dojú kọ, ó sì máa bá wa yanjú ẹ̀.