Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tá a bá fẹ́ káwọn èèyàn fọkàn tán wa, a gbọ́dọ̀ máa ṣohun tó fi hàn pé a ṣeé fọkàn tán. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa mọ ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká máa fọkàn tán ara wa. Bákan náà, a máa mọ àwọn nǹkan táá jẹ́ káwọn ẹlòmíì fọkàn tán wa.