Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Àmọ́, àwọn ọ̀rọ̀ náà “àwọn olódodo” àti “àwọn aláìṣòdodo” tó wà nínú Ìṣe 24:15 àtàwọn ọ̀rọ̀ náà “àwọn tó ṣe ohun rere” àti “àwọn tó sọ ohun burúkú dàṣà” tó wà nínú Jòhánù 5:29 ń sọ nípa ohun táwọn tó jíǹde ṣe kí wọ́n tó kú.