Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nígbà míì, àwọn nǹkan kan máa ń ṣẹlẹ̀ tó lè mú kó nira fún wa láti jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà àti ètò rẹ̀, pàápàá tó bá jẹ́ pé inú ìjọ ló ti ṣẹlẹ̀ sí wa. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò nǹkan mẹ́ta tó lè ṣẹlẹ̀ àti nǹkan tó yẹ ká ṣe ká lè jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà àti ètò rẹ̀.