Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Òfin Mósè sọ pé àgọ́ ìjọsìn ni kí àwọn olórí ìdílé ti máa pa ẹran tí wọ́n máa jẹ. Àmọ́ tí ibi tí ìdílé kan ń gbé bá jìnnà gan-an sí àgọ́ ìjọsìn, olórí ìdílé náà lè pa ẹran náà nílé wọn.—Diu. 12:21.