Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìṣòro lè dé bá wa nínú ayé burúkú yìí, ó dá wa lójú pé Jèhófà máa ran àwa olóòótọ́ ìránṣẹ́ ẹ̀ lọ́wọ́. Báwo ni Jèhófà ṣe ran àwọn ìránṣẹ́ ẹ̀ lọ́wọ́ nígbà àtijọ́? Báwo ló ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ lónìí? Tá a bá kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn tó gbára lé Jèhófà nígbà àtijọ́ àti lóde òní, á túbọ̀ dá wa lójú pé Jèhófà máa ran àwa náà lọ́wọ́ tá a bá gbára lé e.