Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Ẹ máa rí àwọn àpilẹ̀kọ tó máa ràn yín lọ́wọ́ lórí ìkànnì jw.org àti nínú àwọn ìwé wa. Bí àpẹẹrẹ, wo àwọn àpilẹ̀kọ yìí “Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe Lè Tú Ìgbéyàwó Rẹ Ká” lórí jw.org; “O Lè Borí Ìdẹwò!” nínú Ilé Ìṣọ́, April 1, 2014, ojú ìwé 10-12 àti “Àwòrán Oníhòòhò—Ó Léwu Àbí Kò Léwu?” nínú Ilé Ìṣọ́, August 1, 2013, ojú ìwé 3-7.