Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ọ̀rọ̀ tí Pọ́ọ̀lù sọ nígbà tó ń kọ àwọn lẹ́tà rẹ̀ jẹ́ ká rí i pé ó ṣeé ṣe kó ní ìṣòro ojú, ìyẹn sì lè mú kó ṣòro fún un láti kọ àwọn lẹ́tà sí ìjọ, kó sì wàásù bó ṣe fẹ́. (Gál. 4:15; 6:11) Ó sì ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ohun táwọn olùkọ́ èké ń ṣe tí ò dáa ló kó ẹ̀dùn ọkàn bá Pọ́ọ̀lù. (2 Kọ́r. 10:10; 11:5, 13) Ohun yòówù kó jẹ́, ohun tá a mọ̀ ni pé àwọn nǹkan yẹn ò múnú Pọ́ọ̀lù dùn.