Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Lọ́sẹ̀ mélòó kan kí wọ́n tó pàṣẹ náà, àwọn aṣáájú ẹ̀sìn Kátólíìkì gbé àwọn àpilẹ̀kọ gígùn jàn-ànràn jan-anran jáde nínú ìwé ìròyìn láti fi bẹnu àtẹ́ lu àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wọ́n sì tún fẹ̀sùn kàn wá pé ìjọba Kọ́múníìsì là ń ṣojú fún.