Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀pọ̀ ọdún làwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì fi ń fi ohun ọ̀ṣọ́ tó ní àgbélébùú àti adé sí ara aṣọ wọn láti fi dá wọn mọ̀. Àmì yìí sì wà lójú ìwé àkọ́kọ́ ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ fún ọ̀pọ̀ ọdún. Nígbà tó fi máa di ọdún 1935, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ò lo àmì àgbélébùú àti adé náà mọ́.