Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì àtàwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ kárí ayé fi hàn pé a ti wà ní “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn” tó máa “jẹ́ àkókò tí nǹkan máa le gan-an.” (2 Tímótì 3:1) Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa àwọn ọjọ́ ìkẹyìn, wo “Kí Ni Àmì ‘Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn’ Tàbí ‘Àkókò Òpin’?”