Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń tẹ̀ lé òfin tí ìjọba ṣe lórí lílo ìsọfúnni ẹlòmíì tá a bá ń wàásù.