Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń ṣiṣẹ́ ìwàásù wa lọ́nà tó bá òfin mu tó bá kan ọ̀rọ̀ lílo ìsọfúnni ẹlòmíì.