Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Òfin tí ìjọba ṣe yìí gba pé kí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan máa ṣe nǹkan lọ́tọ̀ọ̀tọ̀. Torí náà, ẹ̀yà tẹ́nì kan ti wá ló máa pinnu bó ṣe máa kàwé tó, irú iṣẹ́ tó máa ṣe, ibi tó lè gbé àti ẹni tó máa fẹ́. Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i, ka “What Was Apartheid?” nínú Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti Ọdún 2007 lédè Gẹ̀ẹ́sì.