Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Ọ̀pọ̀ ilé ìwòsàn tàbí àwọn ilé ìtọ́jú míì ló lè tọ́jú ẹni tó bá fẹ́ jáwọ́ nínú àṣà èyíkéyìí. Ẹni kọ̀ọ̀kan ló máa pinnu irú ìtọ́jú tóun máa gbà.—Òwe 14:15.