Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn àlùfáà máa ń gbowó ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ọmọ ìjọ torí wọ́n gbà pé owó yẹn ò ní jẹ́ kí wọ́n jìyà púpọ̀ tàbí kí wọ́n má tiẹ̀ jìyà rárá torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn, tí wọ́n bá dé pọ́gátórì lẹ́yìn tí wọ́n bá kú.