Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Wo ìwé Gbédègbẹ́yọ̀ náà, Encyclopædia Britannica, 2003, wo abẹ́ àgbélébùú, ìyẹn “Cross”; ìwé The Cross—Its History and Symbolism, ojú ìwé 40; àti ìwé The Companion Bible, tí Oxford University Press tẹ̀ jáde, Àfikún àlàyé (appendix) 162, ojú ìwé 186.