Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀pọ̀ nínú àwọn ìtumọ̀ Bíbélì òde òní ni ò lo ọ̀rọ̀ náà “ọ̀run àpáàdì” nínú Ìṣe 2:27. Kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n lo àwọn ọ̀rọ̀ bíi “isà òkú,” (Bibeli Mimọ); “ibùgbé àwọn òkú,” (Yoruba Bible); “ipò-òkú” (The Passion Translation). Àwọn míì kàn tú ọ̀rọ̀ Gíríìkì náà lólówuuru sí “Hédíìsì.”—Holman Christian Standard Bible, NET Bible, New American Standard Bible, English Standard Version.