Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tó o bá ń fẹ́ kúlẹ̀kúlẹ̀ àlàyé nípa ìdí tá a ṣe lo ọdún 607 Ṣ.S.K, wo àpilẹ̀kọ tá a pè ní “Ìgbà Wo Ni Wọ́n Pa Jerúsálẹ́mù Àtijọ́ Run?—Apá Kìíní,” lójú ìwé 26 sí 31 nínú Ilé Ìṣọ́ October 1, 2011 àti Apá Kejì àpilẹ̀kọ náà tó wà lójú ìwé 22 sí 28 nínú Ilé Ìṣọ́ November 1, 2011.