Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ìwé gbédègbẹ́yọ̀ kan tó ń jẹ́ New Catholic Encyclopedia, Ẹ̀dà kejì, Ìdìpọ̀ kẹrìnlá, ojú ìwé 883 àti 884 sọ pé: “Nígbà táwọn Júù pa dà dé láti ìgbèkùn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ki àṣejù bọ bí wọ́n ṣe láwọn ń bọ̀wọ̀ fún orúkọ náà Yahweh, wọ́n wá ń fi ọ̀rọ̀ bí ÁDÓNÁÌ tàbí ÉLÓHÍMÙ rọ́pò rẹ̀.”