Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nínú àwọn ẹsẹ yìí, àwọn Bíbélì kan lo àwọn ọ̀rọ̀ míì dípò “olùgbàlà,” bíi “olùdáǹdè,” “akọgun,” “aṣáájú,” òmíràn tiẹ̀ lo “ẹnì kan.” Àmọ́, nínú èdè tí wọ́n fi kọ Ìwé Mímọ́ lédè Hébérù ní ìpilẹ̀ṣẹ̀, ọ̀rọ̀ kan náà tí wọ́n lò fún àwọn èèyàn yìí ni wọ́n lò láwọn ibòmíì tí Bíbélì ti pé Jèhófà Ọlọ́run ní Olùgbàlà.—Sáàmù 7:10.