Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Wo ìwé náà, Vine’s Complete Expository Dictionary of Old and New Testament Words. Ọ̀rọ̀ Gíríìkì kan náà ni wọ́n lò nínú Mátíù 5:11, tó sọ̀rọ̀ nípa ohun tí Jésù sọ pé àwọn èèyàn máa sọ ọ̀rọ̀ burúkú “lóríṣìíríṣìí” sí àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀.—Bibeli Ìròyìn Ayọ̀.