Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Ẹ̀sìn táwọn ará Samáríà ń ṣe yàtọ̀ sí ẹ̀sìn Júù, àmọ́ wọ́n máa ń tẹ̀ lé àwọn ohun kan tí Òfin Mósè sọ.