Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọlọ́run sọ fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: Ní Ọjọ́ Ètùtù “Kí ẹ̀yin kí ó pọ́n ọkàn yín lójú.” (Léfítíkù 16:29, 31;Bíbélì Mímọ́) Ohun tọ́rọ̀ yìí túmọ̀ sí ni pé kí wọ́n gba ààwẹ̀. (Aísáyà 58:3) Bíbélì Ìròyìn Ayọ̀ sọ ọ́ báyìí pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ gbààwẹ̀.”