Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Ó jọ pé inú ọ̀rọ̀ Hébérù náà neʹtser, tó túmọ̀ sí “èéhù” ni ọ̀rọ̀ náà “ará Násárétì” ti wá.