Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn ará Róòmù ló máa ń fi sítédíọ̀mù díwọ̀n, sítédíọ̀mù kan sì jẹ́ mítà márùnlélọ́gọ́sàn-án (185).