Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ó jọ pé Jónà gba ìtọ́sọ́nà yẹn, inú rẹ̀ sì wá rọ̀, torí pé Ọlọ́run lò ó láti kọ ìwé Bíbélì tó ń jẹ́ orúkọ rẹ̀.