Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Gbólóhùn náà “ẹ̀ṣẹ̀ ìpilẹ̀ṣẹ̀” kò sí nínú Bíbélì. Ká sòótọ́, ẹ̀ṣẹ̀ àkọ́kọ́ tí a ṣàkọsílẹ̀ rẹ̀ nínú Bíbélì ni ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn Sátánì àti irọ́ ńlá tó pa fún Éfà.—Jẹ́nẹ́sísì 3:4,5; Jòhánù 8:44.