Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ó yani lẹ́nu pé Élífásì rò pé ohùn pẹ̀lẹ́ lòun àtàwọn ọ̀rẹ́ òun fi bá Jóòbù sọ̀rọ̀ torí pé wọn ò jágbe mọ́ ọn. (Jóòbù 15:11) Àmọ́ òótọ́ ibẹ̀ ni pé téèyàn ò bá ṣọ́ra, ọ̀rọ̀ téèyàn fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ sọ gan-an lè dunni wọnú eegun.