Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Kódà, àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù lo ọ̀kan lára ọ̀rọ̀ tí Élífásì sọ, ó sì tipa bẹ́ẹ̀ fi hàn pé kò sí irọ́ nínú ọ̀rọ̀ Élífásì. (Jóòbù 5:13; 1 Kọ́ríńtì 3:19) Òótọ́ pọ́ńbélé ni Élífásì sọ, àmọ́ ọ̀nà tó gbà lò ó nínú ọ̀ràn Jóòbù ni kò dáa.