Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Orúkọ Ọlọ́run fara hàn ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún méje (7,000) ìgbà nínú àwọn ìwé Bíbélì ìpilẹ̀ṣẹ̀. Nínú èdè Hébérù, lẹ́tà mẹ́rin ni wọ́n lò fún orúkọ Ọlọ́run. Lédè Gẹ̀ẹ́sì, wọ́n máa ń pe orúkọ Ọlọ́run ní “Jehovah.” Àmọ́, àwọn ọ̀mọ̀wé míì máa ń pè é ní “Yahweh.”