Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ìjọba Ọlọ́run yìí, tá a tún ń pè ní “Ìjọba ọ̀run,” jẹ́ ìṣàkóso kan láti ọ̀run. (Mátíù 10:7; Ìfihàn 11:15) Kristi ni Ọlọ́run fi ṣe Ọba Ìjọba náà. Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe gbogbo ohun tí Ọlọ́run ní lọ́kàn fún ayé. (Dáníẹ́lì 2:44; Mátíù 6:10) Tó o bá fẹ́ àlàyé sí i, wo àpilẹ̀kọ náà, “Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?”