Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Nínú Bíbélì, ọ̀rọ̀ náà “ayé” ń tọ́ka sí àwọn èèyàn tí ò ní àjọṣe kankan pẹ̀lú Ọlọ́run.