Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nínú ọ̀nà ìgbà ìkọ̀wé yìí, lẹ́tà àkọ́kọ́ nínú èdè Hébérù ni wọ́n fi bẹ̀rẹ̀ ẹsẹ kìíní tàbí àpapọ̀ àwọn ẹsẹ tó bẹ̀rẹ̀, lẹ́tà Hébérù kejì ni wọ́n fi bẹ̀rẹ̀ àpapọ̀ ẹsẹ tó tẹ̀ lé e, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ọ̀nà tí wọ́n gbà kọ ìwé yìí máa jẹ́ kó rọrùn fáwọn èèyàn láti tètè rántí àwọn ọ̀rọ̀ inú Sáàmù náà.