Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jèhófà ni orúkọ Ọlọ́run bó ṣe wà nínú lẹ́tà mẹ́rin tí wọ́n fi kọ orúkọ náà lédè Hébérù. Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa ohun tó fà á tí àwọn atúmọ̀ Bíbélì kan fi lo orúkọ oyè náà “Olúwa” dípò orúkọ tí Ọlọ́run ń jẹ́ gan-an, ka àpilẹ̀kọ náà “Ta Ni Jèhófà?”