Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Èdè Hébérù àti Árámáíkì ni wọ́n fi kọ Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù táwọn èèyàn ń pè ní “Májẹ̀mú Láéláé.”