Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Ojú Ìwé Orí
5 1 “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”—Kí Ni Jésù Ní Lọ́kàn?
15 2 “Ọ̀nà àti Òtítọ́ àti Ìyè”
ÌSỌ̀RÍ 1—‘Wá Wo’ Kristi
25 3 “Ẹni Rírẹlẹ̀ ní Ọkàn-Àyà Ni Èmi”
35 4 “Wò Ó! Kìnnìún Tí Ó Jẹ́ ti Ẹ̀yà Júdà”
66 7 ‘Ẹ Ronú Jinlẹ̀ Nípa Ẹni Tó Lo Ìfaradà’
ÌSỌ̀RÍ 2—“Ó Ń Kọ́ni . . . Ó sì Ń Wàásù Ìhìn Rere Ìjọba Náà”
77 8 “Tìtorí Èyí Ni A Ṣe Rán Mi Jáde”
87 9 “Ẹ Lọ, Kí Ẹ sì Máa Sọ Àwọn Ènìyàn . . . Di Ọmọ Ẹ̀yìn”
108 11 “Ènìyàn Mìíràn Kò Tíì Sọ̀rọ̀ Báyìí Rí”
118 12 “Kì Í Bá Wọn Sọ̀rọ̀ Láìsí Àpèjúwe”
ÌSỌ̀RÍ 3—“Ìfẹ́ Tí Kristi Ní Sọ Ọ́ Di Ọ̀ranyàn fún Wa”
139 14 “Àwọn Ogunlọ́gọ̀ Ńlá Tọ̀ Ọ́ Wá”
150 15 “Àánú Ṣe É”
161 16 “Jésù . . . Nífẹ̀ẹ́ Wọn Dé Òpin”