Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
OJÚ ÌWÉ ORÍ
13 2. A Bí Ìjọba Ọlọ́run ní Ọ̀run
39 4. Jèhófà Gbé Orúkọ Rẹ̀ Lékè
49 5. Ọba Ìjọba Ọlọ́run Mú Ká Túbọ̀ Lóye Ìjọba Náà
60 6. Àwọn Oníwàásù—Àwọn Òjíṣẹ́ Ọlọ́run Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú
68 7. Àwọn Ọ̀nà Tá A Gbà Ń Wàásù—Gbogbo Ọ̀nà La Fi Ń Mú Ìhìn Rere Dé Ọ̀dọ̀ Àwọn Èèyàn
78 8. Àwọn Ohun Èlò Iṣẹ́ Ìwàásù—À Ń Tẹ Ìwé Ìkẹ́kọ̀ọ́ fún Lílò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù Kárí Ayé
87 9. Àwọn Àbájáde Iṣẹ́ Ìwàásù—“Àwọn Pápá . . . Ti Funfun fún Kíkórè”
100 10. Ọba Náà Yọ́ Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Mọ́ Nípa Tẹ̀mí
108 11. A Yọ́ Wa Mọ́ Kúrò Nínú Àwọn Àṣà àti Ìwà Kan—Ká Lè Jẹ́ Mímọ́ Bí Ọlọ́run Ṣe Jẹ́ Mímọ́
118 12. A Ṣètò Wa Láti Jọ́sìn “Ọlọ́run Àlàáfíà”
134 13. Àwọn Akéde Ìjọba Ọlọ́run Gbé Ọ̀rọ̀ Lọ Sílé Ẹjọ́
148 14. Ìjọba Ọlọ́run Nìkan Ṣoṣo Là Ń Tì Lẹ́yìn
157 15. Bí A Ṣe Jà fún Òmìnira Láti Lè Máa Sin Jèhófà Láìsí Ìdíwọ́
170 16. Bí A Ṣe Ń Pàdé Pọ̀ Láti Jọ́sìn
182 17. Bí A Ṣe Ń Dá Àwọn Òjíṣẹ́ Ìjọba Náà Lẹ́kọ̀ọ́
194 18. Bí A Ṣe Ń Rí Owó Bójú Tó Iṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run
202 19. Àwọn Ilé Tá À Ń Kọ́ Ń Bọlá fún Jèhófà
209 20. Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tá A Fi Ń Ṣe Ìrànwọ́