Kókó Ẹ̀kọ́ Inú Ìwé
OJÚ ÌWÉ ORÍ
5 1 Àṣírí Kan Ha Wà fún Ayọ̀ Ìdílé Bí?
13 2 Mímúra Sílẹ̀ fún Ìgbéyàwó Aláṣeyọrí
27 3 Kọ́kọ́rọ́ Méjì sí Ìgbéyàwó Wíwà Pẹ́ Títí
39 4 Báwo Ni O Ṣe Lè Bójú Tó Agbo Ilé?
51 5 Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Ìgbà Ọmọdé Jòjòló
64 6 Ran Ọ̀dọ́langba Rẹ Lọ́wọ́ Láti Ṣàṣeyọrí
90 8 Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Agbára Ìdarí Apanirun
103 9 Àwọn Ìdílé Olóbìí Kan Lè Kẹ́sẹ Járí!
116 10 Nígbà Tí Mẹ́ḿbà Kan Nínú Ìdílé Bá Ń Ṣàìsàn
128 11 Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Nínú Agbo Ilé Rẹ
142 12 Ìwọ́ Lè Borí Àwọn Ìṣòro Tí Ń Ṣe Ìdílé Lọ́ṣẹ́
153 13 Bí Ìgbéyàwó Bá Wà ní Bèbè Àtitúká
163 14 Dídàgbà Pọ̀
173 15 Bíbọlá fún Àwọn Òbí Wa Àgbàlagbà
183 16 Wá Ọjọ́ Ọ̀la Wíwà Pẹ́ Títí fún Ìdílé Rẹ