-
Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìyè àti IkúIlé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017 | No. 4
-
-
BÍBÉLÌ JẸ́ KÁ MỌ ÒTÍTỌ́
Ìtàn nípa ìṣẹ̀dá tó wà nínú ìwé Jẹ́nẹ́sísì sọ pé: “Jèhófà Ọlọ́run sì bẹ̀rẹ̀ sí ṣẹ̀dá ọkùnrin náà láti inú ekuru ilẹ̀, ó sì fẹ́ èémí ìyè sínú ihò imú rẹ̀, ọkùnrin náà sì wá di alààyè ọkàn.” Ọ̀rọ̀ Hébérù tá a túmọ̀ sí “alààyè ọkàn” ni ne’phesh, ó sì tún lè túmọ̀ sí “ẹ̀dá tó ń mí.”—Jẹ́nẹ́sísì 2:7.
Bíbélì tipa báyìí mú kó ṣe kedere pé Ọlọ́run kò dá ọkàn tí kì í kú mọ́ wa. Kàkà bẹ́ẹ̀, ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ni “alààyè ọkàn.” Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé kò sí ibì kankan nínú Bíbélì tó o ti lè rí ọ̀rọ̀ tó fi hàn pé ọkàn kì í kú.
-
-
Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìyè àti IkúIlé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017 | No. 4
-
-
Kò sí ibì kankan nínú Bíbélì tó o ti lè rí ọ̀rọ̀ tó fi hàn pé ọkàn kì í kú
-