ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Má Ba Ara Rẹ Lórúkọ Jẹ́
    Ilé Ìṣọ́—2000 | September 15
    • A rán wa létí pé: “Àwọn ènìyàn kì í tẹ́ńbẹ́lú olè kìkì nítorí pé ó jalè láti fi tẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùn nígbà tí ebi ń pa á.” Bí ebi tilẹ̀ ń pa á, “nígbà tí a bá rí i, òun yóò san án padà ní ìlọ́po méje; gbogbo àwọn ohun tí ó níye lórí nínú ilé rẹ̀ ni yóò fi lélẹ̀.” (Òwe 6:30, 31) Ní Ísírẹ́lì ìgbàanì, olè kan ní láti san ohun tó jí padà, kódà bí gbogbo ohun tó ní tiẹ̀ máa bá ọ̀ràn náà rìn.a Ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti ìyà tó tọ́ sí panṣágà ọkùnrin kan, tí kò ní àwíjàre kankan fún ohun tó ṣe!

  • Má Ba Ara Rẹ Lórúkọ Jẹ́
    Ilé Ìṣọ́—2000 | September 15
    • a Ní ìbámu pẹ̀lú Òfin Mósè, olè kan gbọ́dọ̀ san ohun tó jí padà ní ìlọ́po méjì, ìlọ́po mẹ́rin, tàbí ìlọ́po márùn-ún. (Ẹ́kísódù 22:1-4) Ọ̀rọ̀ náà “ìgbà méje” ṣeé ṣe kó túmọ̀ sí ìyà tó kún rẹ́rẹ́, tó lè mú kó san ohun tó jí padà ní ọ̀pọ̀ ìlọ́po.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́