ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ohun Tó Lè Tọ́ Wa Sọ́nà Ayọ̀
    Ilé Ìṣọ́—2006 | June 15
    • Oníwàásù 9:5, 10 sọ pé: “Ní ti àwọn òkú, wọn kò mọ nǹkan kan rárá, . . . Kò sí iṣẹ́ tàbí ìhùmọ̀ tàbí ìmọ̀ tàbí ọgbọ́n ní Ṣìọ́ọ̀lù, ibi tí ìwọ ń lọ.” Kí ni Ṣìọ́ọ̀lù? Ipò òkú ni. Ṣìọ́ọ̀lù tí í ṣe ipò òkú yìí làwọn tó bá kú máa ń wà. Àwọn òkú ò lè ṣe ohunkóhun nínú sàréè, wọn ò lè gbápá, wọn ò lè gbẹ́sẹ̀, wọn ò mọ ohunkóhun bẹ́ẹ̀ ni wọn ò lè ronú ohunkóhun. Bíi pé wọ́n sun oorun àsùnwọra ló rí.a Ohun tí Bíbélì sọ yẹn fi hàn pé Ọlọ́run kì í mú àwọn èèyàn wa tí wọ́n ti kú lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ lọ́run. Kíkú tí wọ́n kú ti mú kí wọ́n di aláìlẹ́mìí nínú sàréè tí wọ́n wà.

  • Ohun Tó Lè Tọ́ Wa Sọ́nà Ayọ̀
    Ilé Ìṣọ́—2006 | June 15
    • a Ìwé gbédègbẹ́yọ̀ Encyclopædia Britannica (2003) sọ pé Ṣìọ́ọ̀lù jẹ́ “ibì kan tí kò ti sí ìrora tàbí ìgbádùn, ìjìyà tàbí èrè.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́