ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Agbára Ìdarí Apanirun
    Àṣírí Ayọ̀ Ìdílé
    • 19. Àwọn àpẹẹrẹ inú Bibeli wo ni ó fi hàn pé kì í ṣe ẹ̀ṣẹ̀ fún ìdílé láti gbádùn ara wọn?

      19 Bibeli ha dẹ́bi fún gbígbádùn ara ẹni bí? Dájúdájú kò ṣe bẹ́ẹ̀! Bibeli sọ pé, “ìgba rírẹ́rìn-ín . . . àti ìgba fífò kiri” ń bẹ.b (Oniwasu 3:4, NW) Àwọn ènìyàn Ọlọrun ní Israeli ìgbàanì, gbádùn orin àti ijó, àwọn eré àṣedárayá, àti àlọ́ pípa. Jesu Kristi re ibi àsè ìgbéyàwó ńlá àti ibi “àsè ìṣenilálejò gbígbórín,” tí Matteu Lefi ṣe fún un. (Luku 5:29; Johannu 2:​1, 2) Dájúdájú, Jesu kì í ṣe abaniláyọ̀jẹ́. Ǹjẹ́ kí a má ṣe ka ẹ̀rín àti ìgbádùn ara ẹni sí ẹ̀ṣẹ̀ nínú agbo ilé rẹ!

  • Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Agbára Ìdarí Apanirun
    Àṣírí Ayọ̀ Ìdílé
    • b  Ọ̀rọ̀ Heberu tí a tú sí “rírẹ́rìn-ín” níhìn-ín, ní ọ̀nà míràn, ni a lè tú sí “ṣíṣeré,” dídáni lára yá,” “ṣíṣàjọyọ̀,” tàbí “gbígbádùn ara ẹni” pàápàá.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́