ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ọ̀rọ̀ Mẹ́rin tí Ó yí Ayé Padà
    Kíyè sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì
    • 12. Ìkùnà àwọn amòye wọ̀nyẹn fi ẹ̀rí kí ni hàn?

      12 Bí àwọn amòye wọ̀nyẹn ṣe di ẹni tí a tú fó nìyẹn, pé ayédèrú ni wọ́n, pé ẹ̀tàn pátápátá ni ètò ẹ̀sìn wọn tí a bọ̀wọ̀ fún jẹ́. Ajánikulẹ̀ gbáà ni wọ́n! Bí Bẹliṣásárì ṣe rí i pé ìgbẹ́kẹ̀lé òun nínú àwọn ẹlẹ́sìn wọ̀nyí ti wọmi, jìnnìjìnnì túbọ̀ bò ó sí i, àwọ̀ ara rẹ̀ sì túbọ̀ ń ṣì lára rẹ̀, kódà “ọkàn” àwọn ènìyàn rẹ̀ jàǹkàn-jàǹkàn “dà rú.”e—Dáníẹ́lì 5:9.

  • Ọ̀rọ̀ Mẹ́rin tí Ó yí Ayé Padà
    Kíyè sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì
    • e Àwọn atúmọ̀ èdè sọ pé ọ̀rọ̀ tí a lò fún “ọkàn . . . dà rú” túmọ̀ sí rògbòdìyàn ńláǹlà, bí ìgbà tí rúkèrúdò bẹ́ sílẹ̀ láàárín àpéjọ náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́