ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jóẹ́lì àti Ìwé Ámósì
    Ilé Ìṣọ́—2007 | October 1
    • 2:32—Kí ni ‘kíképe orúkọ Jèhófà’ túmọ̀ sí? Kíképe orúkọ Ọlọ́run túmọ̀ sí kéèyàn mọ orúkọ náà, kó bọ̀wọ̀ fún un gan-an, kó wá gbára lé ẹni tó ń jẹ́ orúkọ náà, kó sì tún fọkàn tán an.—Róòmù 10:13, 14.

  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jóẹ́lì àti Ìwé Ámósì
    Ilé Ìṣọ́—2007 | October 1
    • 2:28-32. Kìkì ẹni tó “bá ń ké pe orúkọ Jèhófà ni yóò yè bọ́” ní “ọjọ́ ńlá àti ọjọ́ amúnikún-fún-ẹ̀rù ti Jèhófà.” Ó mà yẹ ká kún fún ọpẹ́ gan-an o, pé Jèhófà tú ẹ̀mí rẹ̀ jáde sára onírúurú èèyàn débi pé tọmọdé tàgbà, tọkùnrin tobìnrin, ń sọ àsọtẹ́lẹ̀, ìyẹn ni pé wọ́n ń polongo “àwọn ohun ọlá ńlá Ọlọ́run”! (Ìṣe 2:11) Bí ọjọ́ Jèhófà ṣe ń sún mọ́lé, ǹjẹ́ kò yẹ ká túbọ̀ jára mọ́ “ìṣe ìwà mímọ́ àti àwọn iṣẹ́ ìfọkànsin Ọlọ́run”?—2 Pétérù 3:10-12.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́