ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àpèjúwe Méjì Nípa Ọgbà Àjàrà
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
    • Ṣùgbọ́n, “àwọn tó ń dáko” ṣe àwọn “ẹrú” tí wọ́n rán sí wọn ṣúkaṣùka, wọ́n sì pa wọ́n. Jésù wá ṣàlàyé pé: “Ẹnì kan tó ṣẹ́ kù [fún ẹni tó ni ọgbà àjàrà yẹn] ni ọmọ rẹ̀ ọ̀wọ́n. Òun ló rán sí wọn gbẹ̀yìn, ó ní, ‘Wọ́n máa bọ̀wọ̀ fún ọmọ mi.’ Àmọ́ àwọn tó ń dáko náà sọ fún ara wọn pé, ‘Ẹni tó máa jogún rẹ̀ nìyí. Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká pa á, ogún rẹ̀ sì máa di tiwa.’ Torí náà, wọ́n mú un, wọ́n [sí] pa á.”—Máàkù 12:6-8.

  • Àpèjúwe Méjì Nípa Ọgbà Àjàrà
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
    • Àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn olórí àlùfáà rí i pé ‘àwọn ni Jésù ń fi àpèjúwe yìí bá wí.’ (Lúùkù 20:19) Torí pé Jésù ló “máa jogún” olóko yẹn, àwọn aṣáájú ìsìn yìí túbọ̀ ń wá bí wọ́n ṣe máa pa á. Àmọ́ wọ́n ń bẹ̀rù àwọn èèyàn tó wà lọ́dọ̀ Jésù, torí àwọn èèyàn yẹn gbà pé wòlíì ni Jésù. Torí náà wọn ò lè pa á níbẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́