-
Ọmọ Ọlọ́run Ni “Ìmọ́lẹ̀ Ayé”Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
-
-
Torí pé àwọn kan lára àwọn Júù náà nígbàgbọ́ nínú Jésù, ó sọ fún wọn pé: “Tí ẹ bá dúró nínú ọ̀rọ̀ mi, ọmọ ẹ̀yìn mi ni yín lóòótọ́, ẹ ó mọ òtítọ́, òtítọ́ á sì sọ yín di òmìnira.”—Jòhánù 8:31, 32.
-
-
Ọmọ Ọlọ́run Ni “Ìmọ́lẹ̀ Ayé”Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
-
-
Torí náà, òtítọ́ nípa Ọmọ ló lè mú kí ẹnì kan wà lómìnira kúrò lọ́wọ́ ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ títí láé. Jésù wá sọ fún wọn pé: “Torí náà, tí Ọmọ bá sọ yín di òmìnira, ẹ máa di òmìnira lóòótọ́.”—Jòhánù 8:36.
-