ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jòhánù
    Ilé Ìṣọ́—2008 | April 15
    • 19:11—Ṣé Júdásì Ísíkáríótù ni Jésù ń sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ nígbà tó sọ fún Pílátù nípa ọkùnrin náà tó fa òun lé Pílátù lọ́wọ́? Ó jọ pé kì í ṣe Júdásì tàbí ọkùnrin èyíkéyìí ni Jésù ń sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀, kàkà bẹ́ẹ̀ gbogbo àwọn tó lọ́wọ́ sí ikú rẹ̀ ló ní lọ́kàn. Lára wọn ni, Júdásì, “àwọn olórí àlùfáà àti gbogbo Sànhẹ́dírìn pátá,” títí kan “àwọn ogunlọ́gọ̀” tí wọ́n yí lọ́kàn padà, tí wọ́n sì gbà pé kí wọ́n dá Bárábà sílẹ̀.—Mát. 26:59-65; 27:1, 2, 20-22.

  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jòhánù
    Ilé Ìṣọ́—2008 | April 15
    • 21:15, 19. Jésù bi Pétérù bóyá ó nífẹ̀ẹ́ òun ju “ìwọ̀nyí,” ìyẹn àwọn ẹja tó wà níwájú wọn. Ńṣe ni Jésù ń tipa báyìí tẹnu mọ́ ọn pé ó yẹ kí Pétérù máa fi gbogbo ọjọ́ ayé ẹ̀ tẹ̀ lé òun, dípò kó máa bá iṣẹ́ ẹja pípa lọ. Ǹjẹ́ kí àwọn nǹkan tá a ti gbé yẹ̀ wò nínú àwọn ìwé Ìhìn Rere mú kí ìpinnu wa túbọ̀ lágbára sí i láti nífẹ̀ẹ́ Jésù ju ohunkóhun mìíràn tó lè fà wá mọ́ra lọ. Àní sẹ, ẹ jẹ́ ká máa tẹ̀ lé e nìṣó tọkàntọkàn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́