ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Pọ́ọ̀lù Borí Ìpọ́njú
    Ilé Ìṣọ́—1999 | May 1
    • Àwùjọ àwọn tó ti rẹ̀ tẹnutẹnu náà rí ibì kan sinmi ní erékùṣù táà ń pè ní Màlítà. Àwọn olùgbé ibẹ̀ jẹ́ “àwọn elédè ilẹ̀ òkèèrè,” ní ṣáńgílítí “àjèjì aláìgbédè” là ń pè wọ́n (lédè Gíríìkì, barʹba·ros).c Ṣùgbọ́n àwọn ará Màlítà kì í ṣe òǹrorò èèyàn. Ní òdìkejì ẹ̀wẹ̀, Lúùkù, tó jẹ́ alábàákẹ́gbẹ́ Pọ́ọ̀lù, ròyìn pé wọ́n “fi àrà ọ̀tọ̀ inú rere ẹ̀dá ènìyàn hàn sí wa, nítorí wọ́n dá iná, wọ́n sì gba gbogbo wa pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ nítorí òjò tí ń rọ̀ àti nítorí òtútù.” Pọ́ọ̀lù alára dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Màlítà bí wọ́n ti ń wá igi ìdáná, tí wọ́n sì ń kó igi sínú iná.—Ìṣe 28:1-3, àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé, New World Translation of the Holy Scriptures—With References.

  • Pọ́ọ̀lù Borí Ìpọ́njú
    Ilé Ìṣọ́—1999 | May 1
    • c Ìwé tí Wilfred Funk ṣe, tó pè ní Word Origins sọ pé: “Yẹ̀yẹ́ làwọn Gíríìkì máa ń fi àwọn tí kì í bá sọ èdè tiwọn ṣe, wọ́n a máa sọ pé èdè wọn ń dún bí ‘bá-bá’ wọ́n a sì máa pe ẹnikẹ́ni tó bá ń sọ èdè náà ní barbaros.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́