Àtẹ Àwọn Ìwé inú Bíbélì
Àwọn Ìwé inú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù Ṣáájú Sànmánì (Kristẹni)
| ORÚKỌ ÌWÉ | ÒǸKỌ̀WÉ | IBI TÍ A TI KỌ Ọ́ | ÌGBÀ TÓ PARÍ (Ṣ.S.K.) | ÀKÓKÒ TÓ GBÀ (Ṣ.S.K.) | 
|---|---|---|---|---|
| Jẹ́nẹ́sísì | Mósè | Aginjù | 1513 | “Ní ìbẹ̀rẹ̀” sí 1657 | 
| Ẹ́kísódù | Mósè | Aginjù | 1512 | 1657 sí 1512 | 
| Léfítíkù | Mósè | Aginjù | 1512 | Oṣù kan (1512) | 
| Nọ́ńbà | Mósè | Aginjù àti Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù | 1473 | 1512 sí 1473 | 
| Diutarónómì | Mósè | Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù | 1473 | Oṣù méjì (1473) | 
| Jóṣúà | Jóṣúà | Kénáánì | n. 1450 | 1473 sí n. 1450 | 
| Àwọn Onídàájọ́ | Sámúẹ́lì | Ísírẹ́lì | n. 1100 | n. 1450 sí n. 1120 | 
| Rúùtù | Sámúẹ́lì | Ísírẹ́lì | n. 1090 | 11 ọdún ìṣàkóso Àwọn Onídàájọ́ | 
| 1 Sámúẹ́lì | Sámúẹ́lì; Gádì; Nátánì | Ísírẹ́lì | n. 1078 | n. 1180 sí 1078 | 
| 2 Sámúẹ́lì | Gádì; Nátánì | Ísírẹ́lì | n. 1040 | 1077 sí n. 1040 | 
| 1 Àwọn Ọba | Jeremáyà | Júdà | 580 | n. 1040 sí 911 | 
| 2 Àwọn Ọba | Jeremáyà | Júdà àti Íjíbítì | 580 | n. 920 sí 580 | 
| 1 Kíróníkà | Ẹ́sírà | Jerúsálẹ́mù (?) | n. 460 | Lẹ́yìn 1 Kíróníkà 9:44: n. 1077 sí 1037 | 
| 2 Kíróníkà | Ẹ́sírà | Jerúsálẹ́mù (?) | n. 460 | n. 1037 sí 537 | 
| Ẹ́sírà | Ẹ́sírà | Jerúsálẹ́mù | n. 460 | 537 sí n. 467 | 
| Nehemáyà | Nehemáyà | Jerúsálẹ́mù | l. 443 | 456 sí l. 443 | 
| Ẹ́sítà | Módékáì | Ṣúṣánì, Élámù | n. 475 | 493 sí n. 475 | 
| Jóòbù | Mósè | Aginjù | n. 1473 | Ó ju 140 ọdún láti 1657 sí 1473 | 
| Sáàmù | Dáfídì àti àwọn míì | n. 460 | ||
| Òwe | Sólómọ́nì; Ágúrì; Lémúẹ́lì | Jerúsálẹ́mù | n. 717 | |
| Oníwàásù | Sólómọ́nì | Jerúsálẹ́mù | ṣ. 1000 | |
| Orin Sólómọ́nì | Sólómọ́nì | Jerúsálẹ́mù | n. 1020 | |
| Àìsáyà | Àìsáyà | Jerúsálẹ́mù | l. 732 | n. 778 sí l. 732 | 
| Jeremáyà | Jeremáyà | Júdà; Íjíbítì | 580 | 647 sí 580 | 
| Ìdárò | Jeremáyà | Nítòsí Jerúsálẹ́mù | 607 | |
| Ìsíkíẹ́lì | Ìsíkíẹ́lì | Bábílónì | n. 591 | 613 sí n. 591 | 
| Dáníẹ́lì | Dáníẹ́lì | Bábílónì | n. 536 | 618 sí n. 536 | 
| Hósíà | Hósíà | Samáríà (Agbègbè) | l. 745 | ṣ. 804 sí l. 745 | 
| Jóẹ́lì | Jóẹ́lì | Júdà | n. 820 (?) | |
| Émọ́sì | Émọ́sì | Júdà | n. 804 | |
| Ọbadáyà | Ọbadáyà | n. 607 | ||
| Jónà | Jónà | n. 844 | ||
| Míkà | Míkà | Júdà | ṣ. 717 | n. 777 si 717 | 
| Náhúmù | Náhúmù | Júdà | ṣ. 632 | |
| Hábákúkù | Hábákúkù | Júdà | n. 628 (?) | |
| Sefanáyà | Sefanáyà | Júdà | ṣ. 648 | |
| Hágáì | Hágáì | Jerúsálẹ́mù | 520 | 112 ọjọ́ (520) | 
| Sekaráyà | Sekaráyà | Jerúsálẹ́mù | 518 | 520 sí 518 | 
| Málákì | Málákì | Jerúsálẹ́mù | l. 443 | 
Àwọn Ìwé inú Ìwé Mímọ́ Lédè Gíríìkì Tí A Kọ ní Sànmánì (Kristẹni)
| ORÚKỌ ÌWÉ | ÒǸKỌ̀WÉ | IBI TÍ A TI KỌ Ọ́ | ÌGBÀ TÓ PARÍ (S.K.) | ÀKÓKÒ TÓ GBÀ | 
|---|---|---|---|---|
| Mátíù | Mátíù | Ísírẹ́lì | n. 41 | 2 Ṣ.S.K. sí 33 S.K. | 
| Máàkù | Máàkù | Róòmù | n. 60 sí 65 | 29 sí 33 S.K. | 
| Lúùkù | Lúùkù | Kesaríà | n. 56 sí 58 | 3 Ṣ.S.K. sí 33 S.K. | 
| Jòhánù | Àpọ́sítélì Jòhánù | Éfésù tàbí nítòsí | n. 98 | Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣáájú, 29 sí 33 S.K. | 
| Ìṣe | Lúùkù | Róòmù | n. 61 | 33 sí n. 61 S.K. | 
| Róòmù | Pọ́ọ̀lù | Kọ́ríńtì | n. 56 | |
| 1 Kọ́ríńtì | Pọ́ọ̀lù | Éfésù | n. 55 | |
| 2 Kọ́ríńtì | Pọ́ọ̀lù | Makedóníà | n. 55 | |
| Gálátíà | Pọ́ọ̀lù | Kọ́ríńtì tàbí Áńtíókù ti Síríà | n. 50 sí 52 | |
| Éfésù | Pọ́ọ̀lù | Róòmù | n. 60 sí 61 | |
| Fílípì | Pọ́ọ̀lù | Róòmù | n. 60 sí 61 | |
| Kólósè | Pọ́ọ̀lù | Róòmù | c. 60 sí 61 | |
| 1 Tẹsalóníkà | Pọ́ọ̀lù | Kọ́ríńtì | n. 50 | |
| 2 Tẹsalóníkà | Pọ́ọ̀lù | Kọ́ríńtì | n. 51 | |
| 1 Tímótì | Pọ́ọ̀lù | Makedóníà | n. 61 sí 64 | |
| 2 Tímótì | Pọ́ọ̀lù | Róòmù | n. 65 | |
| Títù | Pọ́ọ̀lù | Makedóníà (?) | n. 61 sí 64 | |
| Fílémónì | Pọ́ọ̀lù | Róòmù | n. 60 sí 61 | |
| Hébérù | Pọ́ọ̀lù | Róòmù | n. 61 | |
| Jémíìsì | Jémíìsì (Àbúrò Jésù) | Jerúsálẹ́mù | ṣ. 62 | |
| 1 Pétérù | Pétérù | Bábílónì | n. 62 sí 64 | |
| 2 Pétérù | Pétérù | Bábílónì (?) | n. 64 | |
| 1 Jòhánù | Àpọ́sítélì Jòhánù | Éfésù tàbí nítòsí | n. 98 | |
| 2 Jòhánù | Àpọ́sítélì Jòhánù | Éfésù tàbí nítòsí | n. 98 | |
| 3 Jòhánù | Àpọ́sítélì Jòhánù | Éfésù tàbí nítòsí | n. 98 | |
| Júùdù | Júùdù (Àbúrò Jésù)) | Ísírẹ́lì (?) | n. 65 | |
| Ìfihàn | Àpọ́sítélì Jòhánù | Pátímọ́sì | n. 96 | 
[Orúkọ àwọn òǹkọ̀wé ìwé mélòó kan àti ibi tí a ti kọ wọ́n kò dájú. Ṣe ni a fojú bu ọ̀pọ̀ nínú àwọn déètì náà, àmì náà l. túmọ̀ sí “lẹ́yìn,” n. túmọ̀ sí “nǹkan bí,” ṣ. sì túmọ̀ sí “ṣáájú.”]